As we enter this new chapter in Lagos, we join the incredible people of our state in celebrating this significant milestone in our political journey.
We pray that Almighty Allah bestows upon you divine wisdom, knowledge, and understanding to elevate the Lagos State House of Assembly to new heights for the benefit of all residents of Lagos State. Amen.
Omo Ojora Apasa
Omo Oyinbo dudu lode iganmu
Omo ofomo foko Toun ti ele idi e
Omo nmoru wa nma se egi
Omo nmoru ti ki run sansan ti ogberi ko mo o pe lesun isu
Omo epiya meta Okan lomi Okan loke Okan ni isasun Iyawo ti ko je ki Iyawo le lo
Omo aja buru iloso won gbe aja ta won fi ra Obo Omo onide ka sa lakobi
Omo o gbe Obirin ta fi owo ra akobi
Omo akobi ni gbe ni Obirin kin gbe ni
Omo irinwo Opa egberun Aje
Omo asiun Lori eru bi eru ba ku a rami…
Aromire Akeruwasa onta ogogbondu
Omo Onile A te jeje a jeji a te girigiri
Omo onitana Akipa…
Omo Oniru
Omo erin to gboku nyin ibon ode
Omo o nta
Omo gbogbondu
Omo akenigbo keru ba ara ona
Omo belu ojilokiti
Omo awonoku komo oju
Oniru Omo ede okun Eja losa
Omo Abisogun Oniru Alabati
omo owori bikale
Adajo n owo eyo
Adajo ba owo nuje Ayinmini oro
Omo olokun
Omo olosa
Omo asehun ma pekan
Omo apekan ma fobinrin je
Omo o bobirin sun dupe ore ana
Omo Sokun Agana Ogun
Omo Ojumo Kan Ogun Kan
Omo Erin J’ogun Ola
Omo Oba Ado
Omo Ibini Arokun Tayo
Omo Ogboni Iduntafa
Omo Atafa Mataro
Omo Atafa Matase
Omobalufon Ni M’oko Ni M’ebi
Omo Ajede Luwasa
Omo Aforesinku
Omo Olugbani Idunmagbo
Omo Erelu Abiye Ilu Eko Tobimo Meji Tofiwon Je Oba Ni Ojo Kan Soso
Omo Olorogun Atebo
Omo Ladega
Omo Babanlamila
Omo Ojigiri Tagiri
Omo Osha Nla Ni Ita Ado
Omo Ibini Arokun Tayo
Iya Mi
Moyo Fun E
Moyo Fun Rami
Leave a Reply